Iporuuru ọkàn: Ajakalẹ àrùn tí ń yọ Nigeria lẹ́nu Olayemi Oniroyin 5/26/2019 07:49:00 am Add Comment Edit Tí a bá ń parọ fún ara wa ni a má fi ọ̀rọ̀ sì abẹ ahọn sọ. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ sì ni wi pe nǹkan burú síi ní fún orile-ede Nàìjíríà. Àpẹẹrẹ wí pé ... Read More
Sàràkí lè dá Buhari lágbo nu Olayemi Oniroyin 7/23/2018 11:10:00 pm Add Comment Edit Inúfu-àyàfu ni ẹgbẹ́ òṣèlú APC wá báyìí pelu ahesọ ọ̀rọ̀ tí ń lọ kiri wí pé, Ààrẹ ilé igbimo asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí kò ní pẹ fi ẹg... Read More
Ìkà tí ẹbi Abiola ṣe fún MKO ju ti IBB àti Abacha lọ Olayemi Oniroyin 6/18/2018 09:43:00 pm Add Comment Edit Ìròyìn tí kárí ayé wí pé wọn ti fi olóògbé Moshood Kashimawo Olawale Abiola jẹ òye idanilọla orile-ede Nàìjíríà tó gaju lọ, GCFR. Ṣùgbọ́n ẹ... Read More
Ìgbà èwe: Mo pàdánù ọrẹ méjì tí mo fẹ́ràn ju Olayemi Oniroyin 5/27/2018 08:32:00 am 1 Comment Edit Ó ní ayajọ àwọn èwe lagbaye. Eléyìí sì. Mú mi rántí Musa, ọrẹ mi ìgbà èwe, ile iwe alakobẹrẹ láti pàdé. Mo fẹ́ràn Musa nítorí wí pé o jẹ ọ... Read More
"Ẹ má gbàgbé ohun tí mo sọ": Ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n JJ Okocha Olayemi Oniroyin 4/02/2018 08:24:00 am Add Comment Edit JJ Okocha ẹni tí wọn fún ni Muhammet Yavuz gẹ́gẹ́ bí orúkọ tuntun ni ilu Turkey nígbà tí wọn fún un ní iwe àṣẹ láti jẹ ọmọ ìlú náà ni kókó ọ... Read More