"Ko si time fun mi rara " - Johnson Adeniyi, oko atijọ Toyin Aimakhu Olayemi Oniroyin 11/24/2016 08:44:00 pm Add Comment Edit Johnson Adeniyi Awon Yoruba bọ, won ni idi isẹ ẹni lati mọni lọlẹ. Johnson Adeniyi to jẹ ọkọ aarọ Toyin Aimakhu ki igbeyawo won to tuk... Read More
Ẹnu ọpẹ Lanre Teriba lẹyin irin-ajo Amerika Olayemi Oniroyin 11/22/2016 01:26:00 pm Add Comment Edit Lanre Teriba Awon Yoruba bọ, won ni ọdẹ to pẹran to setutu nitori eyi ko nitori omiran ni. Ogbontarigi olorin ẹmi, Lanre Teriba, ti ... Read More
Hakeem Effect: Agbaọje onise asaraloge to gbamuse Olayemi Oniroyin 11/14/2016 08:43:00 pm Add Comment Edit Hakeem Effect Ti a ba n so nipa ise asaraloge ninu sinima, eleyii ti rekọja ka kun atike funfun lasan soju osere. Ara isẹ asaraloge ... Read More
Lati bi odun mewaa, Oluwa-si-n-darasi @KunleAfolayan Olayemi Oniroyin 11/08/2016 08:45:00 am Add Comment Edit Awon Yoruba bo,won ni inu eni ki i dun ka pa a mora. Eleyii ni a le fi se apejuwe idunnu Kunle Afolayan, eni ti okiki fiimu re tuntun ... Read More
Ariwo @FunkeAkindele ni won pa niluu Biritiko latari #JenifaInLondon Olayemi Oniroyin 11/07/2016 07:38:00 am Add Comment Edit Lati London wo Manchester niluu Oba Elisabeeti, lati bi ojo kerin to fi wo ojo kefa osu kokanla odun 2016, ariwo oserebinrin ile adul... Read More