Manny Pacquiao ti jasẹ di senato ni Philippines Olayemi Oniroyin 5/21/2016 01:42:00 pm Add Comment Edit Ogbontarigi afese-ku-bi-ojo omo ile Philippines, Manny Pacquiao, ti jawe olubori ninu eto idibo ile igbimo asofin agba ile naa eleyii to... Read More
To ba je wi pe Samuel Okwaraji n be laye ni... Olayemi Oniroyin 5/19/2016 08:41:00 pm Add Comment Edit To ba je wi pe Samuel Okwaraji n be laye, o ni yii ni ko ba pe omo odun mejilelaadota (52). Sugbon iku seka, iku doro, iku o je ki Okwar... Read More
C. Ronaldo fitan balẹ: Aadota goolu lo gba wọle lodun mefa lera won Olayemi Oniroyin 5/16/2016 08:01:00 pm Add Comment Edit Cristiano Ronaldo ti fi itan tuntun balẹ gege bi agbaboolu to gba boolu sanwon tayo aadota fun odindi odun mefa lera won lailabula. Iru i... Read More
Won ti gbade fun Arsenal: Asisat Oshoala fo fayo Olayemi Oniroyin 5/15/2016 04:20:00 pm Add Comment Edit Asisat Oshoala Egbe agbaboolu Arsenal ti awon obirin ti gbegba oroke ninu idije FA CUP ti orileede Biritiko bayii. Aseyori yii lo waye... Read More