Iroyin kan to ti n fo kiri ayelujara wi pe, Sola Kosoko aya Abina sese bimo tuntun ni iwadii itopinpin fihan wi pe, iro patapata ni i...
Read More
Home / Ere
Showing posts with label Ere. Show all posts
Showing posts with label Ere. Show all posts

Ojopagogo seranti iyawo re to ti koja sorun leyin odun merindinlogun
Rasaq Olayiwola ti gbogbo eniyan mo si Ojopagogo se iranti iyawo re to ti silebora. Ki Edua oke ba wa dele fun eni to lo. Atejade Ojopago...
Read More

Sẹun Ẹgbẹgbẹ ti lọ fẹnu gbolẹ niwaju Toyin Aimakhu
Seun Egbegbe ati Toyin Aimakhu Ogbeni Seun Egbegbe to je oko ti Toyin Aimakhu fẹ nikete to kọ Adeniyi Johnson sile, eleyii ti yigi awo...
Read More
Leyin Olumide Bakere, osere tiata mii naa ti wa ninu inira nla
Leyin Olumde Bakare to n gba itoju lowo nile iwosan UCH, Ibadan, Papa Waya naa ti wa lori aisan nla eleyii ti awon ebi re n beere fun ir...
Read More

’E So Fun Omoge Onibadi Olokiki Wi Pe Ko Gbe Ibadi Re Pamo‘ - Alfa Moffy Lati Oshogbo
Jeje ni mo joko sile mi ni irole ana ni ago gasimileti mi ba dun. Nomba lasan lo gbe jade, ko gbe oruko jade. Oju ese ni okan mi ti ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)