To ba je t'IFA gidi to je ojulowo Ifa, taani ko mo Araba Ifayemi Elebuibon?
Read More
Home / Gbajumo Lawujo
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
Ire ayo: Oni ni ojo ibi Big Abass
Oni ni ojo ibi Titiloye Ajiboye titi gbogbo eniyan mo si Big Abass. A ba osere naa yo, igba odun, odun kan ni. Ase
Read More

Lara Olubo loba asiko yii!
Oloju ologbon ti n fogbon tore. Gbogbo eni mo loju ko leniire. Aimoye ika eniyan ni sun ni soosi. Sugbon tOmolara Omobolaji yato ged...
Read More

Bukola Adeeyo: Ojo-ibi Kara ọmọ alagogo idẹ kun fun ẹkọ gidi
Bukola Adeeyo- (Kara) Awon Yoruba bọ, won ni bi ọmọ ẹni ba dara ka wi, ki i sebi ka fi saya. Ọpọ awon eniyan ni won sare sidi isẹ tia...
Read More

Ogo ilẹ Yoruba: Hon Akeem Adeyemi omo Alaafin Oyo pe ẹni ogoji odun (40yrs)
Hon Akeem Adeniyi Adeyemi (Skimeh) Ka bini nile ọla ko ni ka rinrin iyi lawujọ. Aimọye ori-ade ni won ti sọmọluabi nu dẹni yẹyẹ law...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)