Olufemi Davies pe eni aadota odun laye Olayemi Oniroyin 11/07/2017 10:48:00 pm Add Comment Edit Bi won ba ni ki n pe olorin wa. Olayemi oba, mo mojulowo olorin to gbamuse. Oro awada ko, ojogbon to mo'Fa bi Wande omo Abimbola ò pe ... Read More
Emeritus Alhaji: Kola Olootu selenkejọ niluu Saudi Arabia Olayemi Oniroyin 9/09/2017 03:31:00 pm Add Comment Edit Baasoro Ile Yoruba, Alh Kola Olootu Ninu awọn eto Kola Olootu, Oselenkejọ, Oloye yii ti fi igba kan salaye awon nnkan ara-ọtọ to mu a... Read More
Idi ti Yinka Quadri ati Eniola Badmus fi je 6&7 ni yii Olayemi Oniroyin 9/07/2017 10:24:00 pm Add Comment Edit Bi o tilẹ je wi pe awon mejeeji ti se opolopo fiimi to larinrin ti won si gbajumo. Sugbon awon ololufe ise sinima to yanranti ko le gbag... Read More
Itan igbesi aye Sir Shina Peter oba orin Afrojuju Olayemi Oniroyin 6/06/2017 11:18:00 pm Add Comment Edit Sir Shina Peters Eniyan ti yoo pegan oosa ni o ni afin o fin to. Terin ba n lo nigbo, tigbo tiju ni i mola erin. Papalantoro loni ... Read More
Salawa Abeni se ajoyo ojo-ibi Olayemi Oniroyin 5/05/2017 03:42:00 pm Add Comment Edit Queen Salawa Abeni, Gentle Lady, se ajoyo ojo ibi lonii, ojo karun un osu karun odun. A gbadura ire ayo, ifokanbale, alaafia ati ... Read More