JcmcAyodeji tí dàgbà nínú ise ọpọlọ tó fakiki Olayemi Oniroyin 1/17/2018 05:57:00 am Add Comment Edit O wu Èdùmàrè lọ fún JcmcAyodeji Sodiq Olalekan logbon orí. Àgbàlagbà pedepede tí gbogbo ayé ń yewo bí Ifá ni. Ìgbà ilé rẹ kò ní din, àwo il... Read More
Ẹ ṣàánú mi, àìsàn kò jẹ ń gbádùn ara mi" Kemi Olunloyo wá iranlowo owó leyin tó dé láti ẹ̀wọ̀n Olayemi Oniroyin 1/16/2018 03:33:00 pm Add Comment Edit Ẹnikẹ́ni tí ìwọ bá nípa, láti ṣe iranlowo fún, òun ni enikeji rẹ tooju rẹ. Atejade Kemi Olunloyo ni yìí leyin tó dé láti ẹ̀wọ̀n. URGENT: PL... Read More
HBD JayHemKay: Olajumoke Ewatomi gbàrà dá! Olayemi Oniroyin 1/11/2018 09:55:00 am Add Comment Edit Sebi ọdọọdún làá rorogbo. Ọdọọdún báyìí náà là romo òbí lórí àte. Òní ojo kọkànlá oṣù kìíní ọdún táa wá yìí ni Olajumoke Ewatomi ọmọ Ajadi t... Read More
Saraki @55: Ẹja ńlá tí ń danu odò ru gbudugbudu Olayemi Oniroyin 12/20/2017 06:15:00 am Add Comment Edit Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, pé ẹni ọdún márùn-ún-le-ni-aadota (55) lojo Isegun to koja yii, 19/12/17. Aimoye awon ènìyàn n... Read More
Odun mokandinlogbon (29) ni yìí tí Fayose àti aya re ti n bo Olayemi Oniroyin 12/19/2017 04:21:00 pm Add Comment Edit Ẹ kú oriire Read More