Awon Idan, Ara Ati Bebe To Sele Ni Notting Hill Carnival 2014 Ni Ilu London Olayemi Oniroyin 10/21/2014 08:33:00 pm Add Comment Edit Notting Hill Carnival je ajoyo eleyii to maa n waye lodoodun ni ilu United Kingdom. Gege bi itan se fi ye wa, odun 1966 lo bere... Read More
Aworan Omobirin Ti n Ba Kinihun Sore Timotimo Olayemi Oniroyin 10/21/2014 02:49:00 pm Add Comment Edit Awon eniyan kan so wi pe omo eranko wulo nigba mii ju omo eniyan lo. Won ni ti ore ba pe, omo eniyan le gbagbe sugbon aja kii gbagbe oloo... Read More
Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika Tun Jade Lai Wo Komu Olayemi Oniroyin 10/13/2014 08:58:00 am Add Comment Edit Eniyan taa ba lori igi ope, oro re ti kuro ni sara le tabi o le. Ohun to daju ni wi pe omobirin onibadi olokiki ilu Amerika, Kim ... Read More
[Foto] Ogede Agbagba Omokunrin To Yirapada Di Orekelewa Obirin Durosoke Olayemi Oniroyin 9/23/2014 08:29:00 am Add Comment Edit Okunrin ni awon obi re bi saye, sugbon igba to daye ni omokunrin naa gba wi pe asise loje fun oun lati waye gege bi okunrin. Idi ni ... Read More
Ebola Paayan Siwaju Osibitu Ni Ilu Liberia Olayemi Oniroyin 9/12/2014 03:57:00 pm Add Comment Edit #Nnkan Mbe! A fi ki Edua oke saanu ile Adulawo Read More