Yomi Fabiyi tí sìn ìyá rẹ to papoda. Kí Edumare tẹ màmá náà afẹ́fẹ́ réré
Read More
Home / Iroyin
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Sugar ja ni Kano níbi ìgbéyàwó ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano
Ọrùn wọ ipínlẹ̀ Kano lánàá, 3/03/2018, nígbà ti àwọn alágbára, alẹnulọrọ olóṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà sọkalẹ si ipínlẹ̀ náà pelu bàálù orísìírísìí ...
Read More
Ìgbéyàwó láàárín ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano tí gbéra
Fàájì òpin ọsẹ yii yóò fakiki ni ipinle Kano níbi tí Abolaji Ajimobi, ọmọkùnrin gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo, yóò ti má gbé Fateema Ganduje, ọmọbìnrin...
Read More
Toyin Abraham sunkún níbi ètò ìsìnkú bàbà rẹ lánàá
Òkú olówó ọdún kan ni, òkú òtòṣì losu mẹ́fà, òkú ọlọmọ laseesetan. Toyin Abraham (Toyin Aimakhu tẹ́lẹ̀) ti sin bàbà rẹ, Pastor B.E. Aimakhu...
Read More
Ẹ polówó ọjà yín nibi: Irú ọjà wo lẹ́yìn ń tà?
Ni báyìí, àǹfààní tí wá fún yín láti ṣe ìkéde, ipolowo, ìpolongo lórí àwọn ìkànnì wá lórí ayélujára pẹlu irọrun. Ẹyin ẹ kàn kọ̀wé ranse sí ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)