Aisha Buhari aya Ààrẹ Muhammadu Buhari náà wá síbi ayẹyẹ ìgbéyàwó àwọn ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano eléyìí to wáyé lópin ...
Read More
Home / Iroyin
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts

Gómìnà Ajimobi tún dá àríyá ìgbéyàwó eleekeji sílè fún ọmọ rẹ
Leyin ìgbéyàwó to wáyé ní ìlú Kano láàárín Abolaji Ajimobi, ọmọkùnrin gómìnà Ìpínlẹ̀ Oyo ati aya rẹ, Fateema Ganduje to jẹ ọmọ gómìnà ipínl...
Read More
"Àwọn gómìnà ń ṣe ìgbéyàwó fọ́mọ wọn nígbà tí Boko Haram ń ko àwa lọmọ lọ" Olóòtú Sahara Reporters tí fọgba yángan
Oro tún ti gba ibòmíràn yọ. Olóòtú àgbà fún ileese ìròyìn Sahara Reports, Omoyele Sowore tí korò ojú bí bí àwọn adari ṣe peju láti ṣe ìgbéyà...
Read More

ÒNKÀ YORÙBÁ (YORUBA Counting)
COUNTING – ÒǸKÀ YORÙBÁ ÒǸKÀ YORÙBÁ 1– ọ̀kan/ení 2– m éjì 3– m ẹ́ta 4 – m ẹ́rin 5 – m árùn ún 6 – m ẹ́fà 7 – m éje 8 – ...
Read More
Wọn tí si Dangote Business School sì Kano
Aliko Dangote tí si iléèwé tí wọn ti lè kó nípa oko-owo ṣíṣe silẹ ni ìpínlè Kano. Wọn ní N1.2b ni wọn fi kọ ilé ìwé náà.
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)