Njẹ ẹyin mọ wi pe orin lagbara lati dari igbe aye ẹda? Olayemi Oniroyin 5/28/2016 05:26:00 pm Add Comment Edit Ajiyinrere Samuel Oyindamola Orisiirisii ọna ni ijọba okunkun n lo lati ba awon eniyan laye jẹ. Lara irinsẹ pataki kan ti ẹmi okunkun... Read More
Mama Bukola Akinade (Sewele Jesu) ti lo sun ninu Oluwa Olayemi Oniroyin 5/27/2016 04:25:00 am Add Comment Edit Sebi awon Yoruba loni, orisa bi iya ko si laye. N sebi iya ko si le dabi yeye to bi ni lomo. Olubukola Akinade ti gbogbo eniyan mo s... Read More
E wa wo ohun ti omo Wasiu Ayinde mubo lati Canada Olayemi Oniroyin 5/23/2016 10:14:00 pm 1 Comment Edit Okan ninu awon omo King Wasiu Ayinde ti oruko re n je Mustapha Adetunji lo ti ilu Canada de. Dide ti omokunrin naa de, ebun pataki meji l... Read More
Ewi: ENIBAMONURO lati ọwọ Samuel Oyindamola Olabamiji Olayemi Oniroyin 5/20/2016 09:28:00 pm Add Comment Edit Samuel Oyindamola Olabamiji Ti mo ba rẹni Oluwa ọba dalọla. Olayemi akọrin ọba emi ki i binu ori ọla. Sebi ninu ẹran to to... Read More
Njẹ ojulowo orin igbagbọ gidi si wa laye ode oni? Olayemi Oniroyin 5/16/2016 06:43:00 pm Add Comment Edit Bola Aare: Okan ninu awon ojulowo olorin emi gidi Ojulowo orin ẹmi ti n parun. Ti a ko ba kiyesi daada, ojulowo orin ẹmi gidi yoo ... Read More