"Won ko ji iya mi gbe salo o" - Gomina Ambode Olayemi Oniroyin 6/04/2016 12:15:00 pm Add Comment Edit Iroyin kan lo fo jade lau lale ana wi pe, awon kan ti ji iya Gomina Akinwunmi Ambode gbe salo. Sugbon, atejade kan ti jade lati ile i... Read More
Kini Obasanjo lo ba Buhari so lonii ni Aso Rock? Olayemi Oniroyin 6/03/2016 08:48:00 pm Add Comment Edit Won tun ti kofiri Olusegun Aremu Obasanjo nile ijoba apapọ to wa niluu Abuja lonii (June 3). Obasanjo se ipade pọ pẹlu Aare Buhari ni... Read More
Ijoba Ibile Ado Odo/Ota n reti Adewale Dada Olayemi Oniroyin 5/25/2016 12:14:00 pm Add Comment Edit Adewale Dada Thegood Nibayii, Adewale Dada Thegood, gbajugbaja sorosoro ori afefe, ti fi ero re han lati dije fun ipo alaga Ijoba Ibile... Read More
EFCC ti siwee iranti kan Omisore: Won ti gbe WANTED le e lori Olayemi Oniroyin 5/24/2016 05:30:00 pm Add Comment Edit Nibayii, ajo ti n gbogun ti iwa jegudujera,The Economic and Financial Crimes Commission (EFCC), ti gbe atejade kan jade lonii, May 24, el... Read More
Fayose gbe awon ode ibile dide lati koju awon Fulani darandaran Olayemi Oniroyin 5/24/2016 11:50:00 am Add Comment Edit Leyin ikolu awon Fulani darandaran nipinle Ekiti, Gomina Fayose ti gbe awon ode ibile dide pelu atileyin to nipon lati koju awon Fulani d... Read More