
Home / Oro To-N-Lo-Lowo
Showing posts with label Oro To-N-Lo-Lowo. Show all posts
Showing posts with label Oro To-N-Lo-Lowo. Show all posts

'Boko Haram Ko Yato Si Aja Digbolugi To Ye Ki A Fi Bo Ogun Lakaaye' -Femi Fani-Kayode
Ninu ero tuntun Oloye Femi Fani-Kayode, minisita eto irinna ofurufu nigba kan ri gba wi pe awon Boko Haram kii se eni ti eniyan n ba joko p...
Read More
Boko Haram Pa Ogoji Eniyan: Won Pa Soja, Won Pa Olopa Ati DPO Ni Yobe
Oro awon Boko Haram ti di egbirin ote, baa se n pakan lokan tun ru. Awon omo iko Boko Haram tun ti pa awon eniyan bi mokandinlaadota. Ni o...
Read More
"E Yee Wahala Mi Mo. Se Emi Ni Mo Ji Omo Yin Ni Abi Emi Ni Boko Haram Ti Ju Bombu?" - Jonathan
Aare Goodluck Jonathan ti so seti gbogbo awon omo Naijeria wi pe ki awon ara ilu ye e gbogun ti oun mo nipa oro awon omobirin bi igba (200...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)