Awon tisa ipinle Kwara taku sori idasesile ti n lo lowo Olayemi Oniroyin 1/09/2016 05:52:00 pm Add Comment Edit Gomina Abdulfatah Ahmed Idasesile awon oluko alakobere to ti bere lati ojo Aje to koja yii nipinle Kwara ni awon egbe oluko ti tem... Read More
Ambode ti yan oga agba tuntun fun ileewe LASU Olayemi Oniroyin 1/09/2016 05:37:00 pm Add Comment Edit Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode ti yan Ojogbon Olanrewaju Fagbohun gege bi oga agba tuntun fun ileewe Ifafiti ti ipinl... Read More
Senato ipinle Ekiti pin iresi fun awon eniyan bi Fayose Olayemi Oniroyin 1/09/2016 04:02:00 pm Add Comment Edit Awon eniyan ti won gbe ni agbegbe ekun Guusu Ekiti gbajo tilu tifon nigba ti arabirin Biodun Olujimi ti n soju won nile igbimo asofin agb... Read More
Awon agba ti yanju laasigbo to be sile laaarin Olubadan ati Gomina Ajimobi Olayemi Oniroyin 1/09/2016 08:11:00 am Add Comment Edit *Wahala naa sele leyin ti Olubadan fi Ladoja je Osi Olubadan Gomina Abiola Ajimobi Ikunsinu lo bere laaarin Olubadan tile Ibadan... Read More
Won ti fi Ladoja je Osi Olubadan Olayemi Oniroyin 1/01/2016 01:17:00 pm 3 Comments Edit Won ti fi Senator Rashidi Adewolu Ladoja je Osi Olubadan lonii (01/01/16) ni aafin Oba Samuel Odulana Odugade, Olubadan tile Ibadan. Read More