Smiley face
Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi níbi ayẹyẹ ọjọ́ Tinubu

Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi níbi ayẹyẹ ọjọ́ Tinubu

Oluwo tí Ilu Iwo, Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi àti olori rẹ níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Asiwaju Bola Tinubu #Tinubu@66
Read More
Oonirinsa níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Asiwaju Bola Tinubu

Oonirinsa níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Asiwaju Bola Tinubu

Ọ̀rọ̀pọ̀tọyùn ọba àwọn ìlékè, idẹ lọ́wọ́ idẹ léṣẹ̀, adé funfun lẹlẹ, ọ̀pá àṣẹ ń sáná yinginyingin, bàtà Adeyeye nkọ?  Ọba alasọ funfun ọmọ O...
Read More
Lọ́jọ́ tí wọn fi Femi Branch jẹ Jagun Asa

Lọ́jọ́ tí wọn fi Femi Branch jẹ Jagun Asa

Won ni bí a kò ba rí ẹyẹ igun a gbọ́dọ̀ ṣebọ, bí a kò rí ẹyẹ akala a gbọdọ sorò, bí a kò bá ti rí ewé akòko kò sí bá a ti fẹ́ joyè nílẹ̀ yìí...
Read More
O ti jasire: Bukola Oni tí diyàwó tuntun

O ti jasire: Bukola Oni tí diyàwó tuntun

Mi ò lọrẹ to pò, díẹ ni àwọn ọrẹ mi; lára wọn sì ni Bukky wá. Bukky a má lo inú kan, ó nifẹ àwọn ènìyàn, bákan ló jẹ́ akíkanjú obìnrin. Mo...
Read More