Smiley face

Aworan Ojo Isegun: Igbagbo Mi Duro Lori Apata


Mark 9:23

Fun awon ti o ba gbagbo, ohun gbogbo ni sise. Ko si ni si ohunkohun kankan ti won ko ni le se tabi ara ti won ko ni le da.


Igbagbo ni orisun ati opin ohun gbogbo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment