Ko si bi baba eni ti wule ko dagba to, ko si eni ti n fe padanu won. E yi ni lati kede fun araye wi pe Hafiz Oyetoro ti gbogbo eniyan mo si Saka ti padanu baba re, Pa Dauda.
Won ti sin baba agbalagba to rebi agba n re yii ni ilana Musulumi si ilu re to wa ni Iseyin ni Ipinle Oyo.
Ki Edua oke te baba si afefe rere.
0 comments:
Post a Comment