Smiley face

Bamanga Fi Ori Ko Ata Asotele T.B Joshua


 
Ni ibere odun yii, aimoye asotele ni awon eniyan Olorun so nipa ohun ti yoo sele ni odun 2014. Lara iru asotele naa ni eyi ti Wooli TB Joshua ti ijo Synagogue agbaye so.
 
Gege bi oro re, oni aimoye alagbara ni won yoo jabo lori ipo agbara ti won wa ni inu odun 2014.
Asootele naa ti pada se le Bamanga Tukur to je alaga egbe PDP lapapo lori. Yato si wi pe agbara jabo lowo Tukur, won tun ni ko si aye fun lati pejo po se ipade awon alagbara agbaagba egbe PDP eleyii ti won maa n se ninu ile ijoba Aso Rock to wa ni ilu Abuja.
Lara asotele TB Joshua tun ni wi pe wahala yoo sele ninu egbe APC nigba ti won ba fe yan tani yoo soju egbe naa lati dije ipo Aare odun 2015.
 


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment