Smiley face

Mo Dupe Lowo Alara, Mo Dupe Lowo Ajero



Odun ti n pari lo o. Mo fi asiko yii dupe lowo Olorun oba to mu mi ri akoko yii. Bakan naa ni mo si n dupe lowo eyin ololufe wa pata nile-loko. Kosi ni je didun inu mi ki n gbagbe awon ti won se atileyin fun mi nigba gbogbo. Odun 2014 je odun to dara, mo si lero wi pe 2015 maa tun larinrin ju ero gbogbo wa lo. Bi eniyan ba gunyan to fele bi eti ti o ba reni je iru obe bee yoo pada baje ni. Bi mo ko iroyin ti e ba ka kii se wi pe emi ni mo pegede julo ninu ede lilo tabi agbekale to yaayi julo, ife lasan le ni si wa. Olorun oba ko ni pana ife naa rara. Ni agbara Olorun ajosepo wa ko ni baje.

Inu mi o dun lati mo awon ibi taa ku si ati awon atunse ti e fe ka se. E se gan-an.

08073617207

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment