Wasiu Ayinde baba YOMADE pe eni odun mejidinlogota (58) lana ode yii ni awon irawo osere bi Fathia Balogun, Muyiwa Ademola, Femi Adebayo ba pawọpọ se ayeye naa fun-un ni oruko egbe won ti won pe ni Unique Charitable Foundation. Ile itura Protea to wa ni Ikeka ni faaji na ti waye.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment