Awon Ero Bi Ero Mecca Jade Wa Wo Buhari Ni Ilu Kano Lonii Olayemi Oniroyin 1/20/2015 11:35:00 pm Add Comment Edit Ilu Kano gbalejo Muhammadu Buhari lonii nibi to ti n so fun awon eniyan wi pe yato si ibo won ti won fe di, won tun gbodo ri daju wi pe w... Read More
Mo Dupe Lowo Alara, Mo Dupe Lowo Ajero Olayemi Oniroyin 12/29/2014 12:21:00 pm Add Comment Edit Odun ti n pari lo o. Mo fi asiko yii dupe lowo Olorun oba to mu mi ri akoko yii. Bakan naa ni mo si n dupe lowo eyin ololufe wa pata ni... Read More
Abiodun Alaso Asiko Olayemi Oniroyin 12/28/2014 07:55:00 pm Add Comment Edit Omidan Abiodun lo ni ka kede re wi pe 'otito loba awure' Bi eniyan ba fi otito inu sise laye dandan ni ko jere to po. ... Read More
Laarin Ooni Ife ati Alaafin Oyo, Ija Sese Bere Ni o Olayemi Oniroyin 12/28/2014 02:07:00 pm Add Comment Edit Awọn kan ti n gbiyanju lati se alaye itunmọ Yoruba leyin atotonu awon onimọ kan ti won gba wi pe ohun to fẹ to jin bi omi okun ni Yor... Read More
Igbe Aye Wale Dada Gege Bi Oniroyin Olayemi Oniroyin 10/29/2014 11:41:00 am Add Comment Edit Yara Agbara Ile Ise Redio Odun kini mi ni ile eko giga je akoko ti mi o le gbagbe laelae. Gbogbo ara ni mo fi sise alakada nitori wi pe... Read More