Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72) Olayemi Oniroyin 9/19/2015 08:00:00 am Add Comment Edit Olatunbosun Oladapo Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba ... Read More
Olayemi Oniroyin lori redio Olayemi Oniroyin 9/17/2015 06:33:00 am 2 Comments Edit Mi o tile mo ohun to gbe mi de kolo oro (studio) lojo naa lodun 2011. Igba ti mo ji laaro yii ni mo tun tule kan an, mi o tile mo wi pe ... Read More
Ogun Omode Ko Le Sere Fun Ogun Olayemi Oniroyin 9/11/2015 01:52:00 pm Add Comment Edit O je ohun to ba ni lokan je, eyi si wa lara iriri to seese ki n maa gbagbe laelae. Akiyesi igbe aye fi ye mi wi pe aimoye imo iyebiye ... Read More
Omo Naijeria Setan Lati Dije Fun Ipo Aare Orileede Spain Olayemi Oniroyin 9/10/2015 09:37:00 am Add Comment Edit Helen Mukoro Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ip... Read More
Asa Ti O Fa Wa Lete Ya Ti Wo Naijeria Olayemi Oniroyin 9/09/2015 09:09:00 am Add Comment Edit Awon onimo eda-ede ti a mo si linguistiiki (imo nipa iseda ede) gba wi pe ohun elemi ni ede je. Eleyii lo fa ti a fi ni awon ede atijo... Read More