Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (1) Olayemi Oniroyin 7/01/2016 03:00:00 pm Add Comment Edit #AyeOlabisiK @OlayemiOniroyin Itan igbesi aye Olabisi K (1) Awọn Yoruba ni oju ẹni maa la, dandan ni ki oju naa riyọnu. Itan... Read More
Iriri mi pelu omoge oniparaga 2 Olayemi Oniroyin 5/14/2016 08:41:00 pm Add Comment Edit Ẹ kaabọ! Ma rọyin lati ka IRIRI MI PẸLU ỌMỌ ONIPARAGA 1 ki ẹ to tesiwaju pẹlu apakeji to jẹ asekagba. Ẹ le ka alaye naa NIBI . Ti ẹ... Read More
Iriri mi pelu omoge oniparaga 1 Olayemi Oniroyin 5/14/2016 09:27:00 am Add Comment Edit Iriri mi pelu omoge oniparaga 1 O sẹburu ọna jade sita gbangba, emi n bọ latoke wa nigba ti oun gba isalẹ bọ wa soke. Ọọkan rere lo... Read More
Enikan Pataki Ti E Gbodo Mo Ki Odun Yii To Pari Ni Yii Olayemi Oniroyin 9/05/2015 10:46:00 am Add Comment Edit Leta isale yii ni mo rigba lowo Ogbeni Kayode A. ti won gbe ni Ketu to wa ni Ipinle Eko. Sugbon ki n to tesiwaju, gege bi oniroyin, mo... Read More
Won Ti Fun Olayemi Oniroyin Ni Kaadi Omo Egbe PDP Lati Tako Buhari? Olayemi Oniroyin 9/04/2015 01:35:00 pm Add Comment Edit A bi eyin ko ti gbo, wi pe awon eniyan ti n fesun kan mi wi pe egbe PDP ti fun mi ni kaadi omo egbe won lati le maa tako ijoba APC to wa... Read More