Aimoye awon eniyan ni won ba Alagba Adeleke Ademola yo lanaa,16-06-2016, fun ayajo ojo ibi won to ko. Bi awon eniyan se n se adura ...
Read More
Home / Gbajumo Lawujo
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
Ojo ibi Ilumoka Presenter wole sinu Ramadan
Waheed Akintayo, sorosoro ori afefe, ti gbogbo eniyan mo si Ilumoka Presenter le lodun lonii ojo kerinla osu kefa odun. Igba odun, odun...
Read More
Dbanj omo olojo-ibi ti gbegba ope
Oladapo Daniel Oyebanjo ti gbogbo eniyan mo si Dbanj, ogbontarigi onkorin ile Naijiria, le lodun lonii ojo kesan-an osu kefa odun.
Read More

Igbeyawo Ọmọọba Kazeem Akadi dun yungbayungba bi oyin
Ọmọọba Kazeem Akadi ati Opeyemi Gbogbo wa pata la wa n'Ibadan lopin ọsẹ to kọja (05-06-16) lati ba Ọmọọba Kazeem ati aya rẹ, Ọpeye...
Read More

Baasọrọ Ile Yoruba: Olubadan fi Kola Olootu joye
Baasọrọ Ilẹ Yoruba, Otunba Kola Olootu Ka ma parọ, oloju alagbara to le gbe olumọ sare. Oloju ẹni le fọwọ lasan fọnna ayafi ẹni ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)