Adegbodu Twins: Ojo ibi awon omo majẹmu wọle de Olayemi Oniroyin 10/04/2016 03:06:00 pm Add Comment Edit Eniyan ti Olorun da ko se farawe. Alagbara ni Olorun ọga ogo, bo se wu u lo n sọla. Talo fẹ bi Oluwa lẹjọ ? Ẹni ti Oluwa n fẹ dabi... Read More
Bayii ni Tunde Kelani se ki Kunle Afolayan ku ojo ibi Olayemi Oniroyin 10/01/2016 02:19:00 pm Add Comment Edit Ogbon ojo osu kesan-an odun 1974 ni won bi Kunle Afolayan saye. Inu odun 2016 yii lo si pe eni odun mejilelogoji (42) Read More
Awon omo Aina ti dagba: Odun ibeji wole de Olayemi Oniroyin 9/15/2016 06:20:00 am Add Comment Edit Ojo ti won bi Taiwo saye ni won bi Kehinde, omo meji to waye leekan soso ni Yoruba n pe n'Ibeji. Sebi Taiwo lo saaju ki Kehinde ... Read More
Odun keje pe leyin iku Gani Fawehinmi Olayemi Oniroyin 9/05/2016 10:03:00 am Add Comment Edit To ba je wi pe a ki i ku laye, awon ara igbaani da? To ba je wi pe eni wa saye kii ronu, se awon ara atijo ko ba si wa lojude. Oku o... Read More
Wemimo pada domo tuntun a ri gbejo Olayemi Oniroyin 9/02/2016 12:22:00 pm Add Comment Edit Eniyan le fi owo ra aimoye ore ni awon akoko kan, eniyan si le fi owo ra okiki ni awon igba die, sugbon aimoye nnkan lo wa laye ti eniya... Read More