Olori Alaafin Oyo sojo ibi odun metadinlogbon (27) Olayemi Oniroyin 11/03/2016 06:07:00 pm Add Comment Edit Olori Olaitan Badirat Adeyemi, olori to kere julo laafin sojo ibi odun metadinlogbon (27) lonii. Se e ko gbagbe wi pe, ojo keedogun ... Read More
Madam Aderemi Adeyinka Aromolaran @ 60 Olayemi Oniroyin 11/02/2016 09:44:00 pm Add Comment Edit Madam Aderemi Aromolaran Awon Yoruba bo, won ni eniyan taa fun leran ti o tayin, bi won fun eni naa lomo ko ni moore. Idunnu nla lo s... Read More
Ojo-ibi Aderonke: Ronishratis di omo tuntun arigbejo Olayemi Oniroyin 10/31/2016 06:58:00 am Add Comment Edit Aimoye eranko nla lo wa ninu igbo, sebi o wu Edumare lo de kinihun lade oba. Aimoye oniroyin alaso oge lo po nile yii, sugbon ojulowo wo... Read More
Mr Latin le lodun lonii: Ire ayo fun omo olojo-ibi Olayemi Oniroyin 10/15/2016 01:00:00 pm Add Comment Edit Bolaji Amusan ti gbogbo eniyan mo si Mr. Latin le lodun lonii. Gbogbo wa la ba osere naa yoo fun odun tuntun to ba laye. Igba odun,... Read More
Ojo ayo Laide Bakare wole de: Ọmọ ọlọjọ-ibi fo fayọ! Olayemi Oniroyin 10/07/2016 01:18:00 am Add Comment Edit Lara idunnu eda laye ni idasi Olorun ọba, aabo, alaafia, owo, ayọ ati ifokanbalẹ. Kosi eyi ninu awon nnkan wonyii ti Olorun ko fi seke L... Read More