Ẹgbẹrun mẹrin ekute ti kọja sọrun niluu Eko Olayemi Oniroyin 1/31/2016 03:32:00 pm Add Comment Edit Ẹgbẹ oṣiṣẹ alaabo ilera ayika, Environmental Health Officers Association of Nigeria, ẹka ti ilu Eko, ti kede wi pe, awọn ekute bi ... Read More
Bayii ni ẹ ṣe le ṣe iwosan fun ọmọ to ni giri. Olayemi Oniroyin 1/30/2016 03:04:00 pm 1 Comment Edit Ìtọ̀ idi iya ọmọ naa la maa kan diẹ si lẹnu, oju ati furọ ọmọ naa. Bakan naa ni a ma fi itọ naa pa gbogbo omo naa lara. Ti a ba se e... Read More
Ọna-abayọ lori aisan ẹjẹ riru, Ijaya (hypertension) ni yii Olayemi Oniroyin 1/27/2016 06:43:00 pm 2 Comments Edit Lati gbogun ti aisan ejeruru ti awon eleyinbo n pe ni hypertension, awon eroja ti a ma lo niwon yii: 1 Ayu meta 2 Igo omi osan w... Read More
“Ona ti a gba yanju Ebola ma yato si ti iba Lassa”- Ojogbon Adewole Olayemi Oniroyin 1/24/2016 10:11:00 pm Add Comment Edit Ojogbon Isaac Adewole Ijoba apapo labe akoso Aare Muhammadu Buhari tun ti fi awon ara ilu lokan bale nipa akitiyan won lati kase... Read More
Bill Gates towo bo iwe adehun pelu Dangote Olayemi Oniroyin 1/24/2016 02:20:00 pm Add Comment Edit Dangote ati Gates Bill Gates, eni ogota odun (60yr) to tun je okunrin to lowo ju lagbay e, ti wo ilu Naijiria lati towo bowe ade... Read More