Awon Omo Akin Fi Owo Lasan Gba Ibon Lowo Ole Olayemi Oniroyin 8/19/2014 07:20:00 am Add Comment Edit Won ti setan bayii lati fun awon omokunrin meji kan ni ami-eye akinkanju pelu bi won se woya ijakadi pelu okunrin odaran olosa kan el... Read More
Ibadi Yakata Ni Won Fi N Polowo Orin Olayemi Oniroyin 8/18/2014 10:52:00 pm Add Comment Edit Asa awon omo olorin ilu Amerika ni awon omobirin olorin Nigeria naa n tele bayii. Ara won ni won fi n gbe ise won laruge. Lara awon omo o... Read More
Awon Iroyin Gbankogbi Lati Aaringbungbun Asia -Apa Keji Olayemi Oniroyin 8/17/2014 12:19:00 pm Add Comment Edit Mo ti mu Apa Kini wa fun yin tele, Ti e ko ba ti i kaa, E le ka iroyin naa [ NIBI ]. E yii ni awon iroyin gbankogbi marun-un mii lati apa As... Read More
Baalu Oludije Fun Ipo Aare Ja Olayemi Oniroyin 8/13/2014 06:54:00 pm Add Comment Edit Okan ninu awon oludije fun ipo Aare ilu Brazil, Eduardo Campos ti je Olorun nipe losan oni nigba ti baalu jeeti re jabo loju ofurufu ... Read More
Awon Oyinbo Alawo Funfun N Pariwo Rauf Aregbesola Leti Omi Olayemi Oniroyin 8/11/2014 03:14:00 pm Add Comment Edit Ilu Seychelles ni Kunle ati Gabriel Afolayan wa bayii. Se e ranti ofofo ti mo tu fun yin nigba kan wi pe imule egbe APC ni Kunle Afolayan... Read More