Aimoye Awon Eniyan Ni Won Koja Sorun Lojo Odun Ni Ilu China Olayemi Oniroyin 1/01/2015 02:48:00 am Add Comment Edit Awon eniyan bi marunlelọgbọn (35) ni won ti tẹ pa bayii ni ilu Shanghai to wa ni China nigba ti enikan fọn owó ayederu kan soke ti gbogbo... Read More
Won Ti N Ko Oku Awon Eniyan To Sagbako Ninu Baalu AirAsia To Ja Olayemi Oniroyin 12/31/2014 12:13:00 pm Add Comment Edit Won ti bere si ni ko oku awon eniyan to sagbako ninu baalu AirAsia pada wa sile nigba ti won ri ibi ti baalu na jasi ninu omi okun. Oku at... Read More
Awon Eniyan Ti Won Ni Ebi Ninu Baalu AirAsia To Poora Ti Wa Ninu Ibanuje Olayemi Oniroyin 12/28/2014 10:31:00 pm Add Comment Edit Inu ibanuje nla ni awon eniyan ti won ni ebi ninu Baalu AirAsia to gbera ni Indonesia to n lo si ilu Singapore, eleyii to poora laro o... Read More
Won Ti Dajo Iku Fun Omo Nigeria Ni Ilu Malaysia Olayemi Oniroyin 11/27/2014 02:32:00 pm Add Comment Edit Ile ejo to gaju ni ilu Malaysia ti dajo iku fun Abuchi Ngwoke, eni odun marunlelogbon (35) ni ilu Malaysia pelu esun wi pe o gbe ogun olo... Read More
Se Ki Won Pa Ni Abi Ki Won Fi Sewon Gbere: Maanu To Pa Omo Odun Mokanla Leyin To Ba Sun Tan? Olayemi Oniroyin 11/03/2014 07:59:00 am Add Comment Edit Ogbeni ti oruko re n je Charles Warner lati Ipinle Oklahoma to wa ni Ilu Amerika lo ba Adrianna Waller, omo odun mokanla to je omo orebiri... Read More