Baalu Ti Sina Ni Ilu New York Olayemi Oniroyin 3/05/2015 09:35:00 pm Add Comment Edit Baalu Delta ni iroyin kan wa wi pe osina oju ona asaregba nikete to ba kale ni papako ofurufu LaGuardia to wa ni New York lonii. Eniken... Read More
Ọjọ Ti Wọn Bi Misao Okawa Ni Ilu Japan Ni Won Bi Omoiyashina Ni Ilu Nigeria Olayemi Oniroyin 3/04/2015 09:50:00 pm Add Comment Edit Iya arugbo eni Odun metadinlọgofa 117 se ojo ibi lonii ni ilu Japan Read More
Won Se Igbeyawo Alarinrin Ninu Poosi Ni Ilu Thailand Olayemi Oniroyin 2/16/2015 08:40:00 pm 1 Comment Edit Bayii la n se ni ile wa, eewo ibo mii ni. Awon toko-taya kan ti se igbeyawo alarinrin eleyii ti won se ninu poosi niwaju orisa Takien to w... Read More
Awon Omo Alakatakiti Esin Islam Ti Pa Kristeni Mokanlelogun (21) Olayemi Oniroyin 2/16/2015 06:53:00 pm Add Comment Edit Awon omo alakatakiti esin musulumi ti se afihan bi won se dunbu awon kristeni omo ilu ijibiiti mokanlelogun. Read More
Eyin Ati Idi Mi Lelejo- Onkorinbirin Ilu Amerika Olayemi Oniroyin 1/20/2015 09:55:00 pm Add Comment Edit Amber Rose, gbajugbaja onkorin takasufe ilu Amerika si wa leti odo ni ilu Miami nibi to ti n jaye alatika. Ibe naa ni Omobirin yii ti juk... Read More