Omoge Olomu Nla N Wa OkoTi O Ma Je Igbadun Eru Aya Re Olayemi Oniroyin 3/14/2015 11:34:00 pm Add Comment Edit Eniyan to koko kola, ika ni won fi se fun-un. Sugbon igba to ya ni ohun itiju ojosi pada wa di ewa. Bee gele lori pelu Kristy Love, eni o... Read More
Awon Obirin Onisan Lapa Ti Gba Ijoba Ni Ilu Australia Olayemi Oniroyin 3/14/2015 10:05:00 pm Add Comment Edit Idije okunrin ati obirin alagbara-kaka-onisan-leyin-orun ti waye ni ilu Australia eleyii ti won se lati fi bu ola fun Arnold Schwarzen... Read More
Kini Oba Lamidi Tun Wa Se Ni Ilu London Pelu Awon Olori? Olayemi Oniroyin 3/14/2015 09:34:00 pm Add Comment Edit Oba Lamidi ni Alaafin asiko yii. Bi won ba n pe oba l'Alase-Ekeji Orisa bi ti Lamidi ko. Oosa gan-angan ni Lamidi. Aye ye Lamidi Olay... Read More
Won So Omo Odun Mesan-an To Jale Somi Ni Ilu China Olayemi Oniroyin 3/14/2015 09:12:00 pm Add Comment Edit Awon Yoruba ni airin jinna lairi abuke okere, ti eniyan ba rin titi yo ri ibi won ti n fi odo ibile jeun. Ni abule kan to wa ni ilu China ... Read More
Asiri Iyawo Ile To Yanle Ti Tu Sowo Oko: Ohun Ti Oko Re Se Fun Ni Yii Olayemi Oniroyin 3/14/2015 09:06:00 pm Add Comment Edit Fidio awon aworan yii lo ti di gbajugbaja lori ikanni Youtube nibi ti okunrun kan ti n koya fun obirin kan. A ko le so pato ohun to sele ... Read More