Chukwudi, omo odun mejidinlogbon (28)ti padanu emi re leyin igba to ta kidinrin re ni milionu mefa owo naira (N6million)niluu Malaysia ...
Read More
Home / Iroyin Okeere
Showing posts with label Iroyin Okeere. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Okeere. Show all posts
Aso Oge Tuntun Nicki Minaj Pelemo
Gbajugbaja onkorin ile Amerika, Nicki Minaj ti ranse ope si sabere-dowo-di-telo to ba ranse re tuntun eleyii to wo lo sode lana.
Read More
Se E Ti Gbo Ohun Ti Aare Ilu Mali So Nipa Davido Omo Baba Olowo?
Dafiidi Adedeji omo Adeleke ti gbogbo eniyan mo si Davido ti kuro lomode ti n fi igba kekere bomi mu leti odo. Bo tile kere loju, okiki,...
Read More
Odun Erofo Ni Ilu South Korea Ti Kari Aye
Odun erofo to maa n waye niluu Boryeong to wa ni orileede South Korea ti di gbajugbaja ti awon eniyan maa wa pewo bi iran lati awon o...
Read More
Ukwu To Tobi Ju Ni Ilu Ghana Ni Yii: Kaka Nla Ti N Jani Laya Bi Oke. Yeepa!
Matilda Quaye Awon Yoruba ni ohun to ba joniloju ni i yanilenu. Ibaradi Matilda Quaye omo ilu Aganyi, ibadi omoge onise oge to ohun t...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)