Omowe Adesina fi geesi ko ede Yoruba pombele Olayemi Oniroyin 1/22/2016 04:06:00 pm Add Comment Edit Omowe Oluwole Adesina Tiwa-n-tiwa takisa taatan. Omowe Wole Adesina ti se agbekale iwe eko ede Yoruba pelu ede geesi to pegede fun ... Read More
Olubadan ti gbe aafin re lo salakeji Olayemi Oniroyin 1/20/2016 09:02:00 am Add Comment Edit Oba Samuel Odulana Odugade 1 Olubadan ti goke aja lo! Oba Samuel Odulana Odugade 1 ti lo ba awon babanla re. Gbogbo Ibadan, e ku arafe... Read More
Ooni tuntun pade Alaafin fun igba akoko niluu Oyo [FOTO] Olayemi Oniroyin 1/17/2016 06:30:00 pm Add Comment Edit Ife ati isokan ti n pada sile Yoruba. Ooni tuntun wo Ilu Oyo, Alaafin si fi erin ati idunnu pade re. Eleyii waye nibi ayeye odun marunlel... Read More
Ayeye odun marunlelogoji lori oye: Alaafin Oyo gbarada! Olayemi Oniroyin 1/17/2016 05:00:00 pm Add Comment Edit *Oba Lamidi sodun ola, asa ati ewa ile Yoruba *Aimoye ero repete lojude Alaafin Oyo *Akewi ni Alaafin rekoja igbakeji Orisa I... Read More
"Dasuki ko pin wa ninu $2.1b nipinle Oyo" - Alaafin Lamidi Olayemi Oniroyin 1/16/2016 06:33:00 pm Add Comment Edit Oba Lamidi Adeyemi III Awon igbimo lobaloba ipinle Oyo ti je ko ye gbogbo eniyan wi pe, kosi oba kan nipinle Oyo to gba ninu $2.1bn to... Read More