Eleyii to kere ju, lo buru ju lo Olayemi Oniroyin 4/11/2016 03:33:00 pm Add Comment Edit Eleyii to kere ju, lo buru ju lo Eran nla, eran agbija, leran ti won pe ni kunnugba. Awon agba ode gba wi pe, eniyan bi meje (7) l... Read More
Tomode ba subu… Olayemi Oniroyin 3/20/2016 09:10:00 pm Add Comment Edit Ni awon akoko kan ninu igbesi aye wa, o ye ki a maa duro lati se asaro ati arojinle nipa awon igbese wa gbogbo. Se a n tesiwaju ni a... Read More
Akoko eda mbe lowo Oluwa oba Olayemi Oniroyin 3/14/2016 09:04:00 am Add Comment Edit Olajumoke Orisaguna E ku asiko yii, eyin eniyan mi. Nje eyin tile mo wi pe oju ojo ilu Kenya n fi wakati meji (2hrs) sare ju til... Read More
Ipo wo ni iwo fe wa ninu awon olowo ile Afirika? Olayemi Oniroyin 3/05/2016 08:30:00 pm Add Comment Edit Mike Adenuga Ni owuro yii, mo fi akoko mi sile lati ka nipa aseyori Mike Adenuga, alase ati oludari ile ise ibanisoro Gbobacom. Ohun t... Read More
Olajumoke omo oniburedi Olayemi Oniroyin 2/28/2016 09:18:00 pm Add Comment Edit Olajumoke Orisaguna Opolopo ni i pokiki Olajumoke Orisaguna omo oniburedi gege bi oloriire ti Edumare da lola ojiji pelu bo se se ... Read More
Falana gbo tie… Olayemi Oniroyin 1/24/2016 10:22:00 pm Add Comment Edit Awon Yoruba ni tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Lose to koja lo loun ni mo n so idi pataki ti a fi gbodo maa fi o ker... Read More
Tina ba n joni, ti n jo omo eni… Olayemi Oniroyin 1/12/2016 08:47:00 pm Add Comment Edit #ogulutu #13 Owo tabua le mi n fe... Odun tuntun ti bere. Bi eniyan se ipinnu, bi eniyan gbadura dola, ti eni naa ko ba gbe igbe... Read More
Igbese, akoko ati agbara fun odun 2016 Olayemi Oniroyin 12/26/2015 10:04:00 pm Add Comment Edit #ogulutu #12 Ti eniyan ba fi opolo sinu ikoko-isebe kan ti omi kun inu re, ki eniyan wa gbe ikoko naa ka ori ina. Bi ina se n jo, t... Read More