A bi eyin ko ti gbo, wi pe awon eniyan ti n fesun kan mi wi pe egbe PDP ti fun mi ni kaadi omo egbe won lati le maa tako ijoba APC to wa...
Read More
Home / Yoruba
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Won Ti Kilo Fun Olayemi Oniroyin Lori Oro Funke Akindele ati Toyin Aimakhu
Laipe yii ni mo se afihan aso oge Funke Akindele eleyii to fi sara niluu London nibi to ti lo se ayeye ojo ibi re to ko ninu osu to koja...
Read More
Morufa Eko 14: Ewon Odun Mewaa Pelu Ise Asekara
Sii Olayemi Oniroyin Agbaye Leta eleekerinla (14) mi ni yii, eleyii ni maa si fi kadi itan igbesi aye mi ti mo ti n ba a bo fun igba...
Read More
Morufa Eko 13: Asiri Oko Anti Mi Tu Sowo Awon Olopaa
E ku deede iwoyii eyin ololufe wa. E mi Morufa naa ni mo tun un ki yin. E ku ifomoniyanse. Se e o gbagbe ibi ti mo ba alaye mi de...
Read More
Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri: Jenifa Pe Omo odun Mokandinlogoji (39)
Aworan Funke Akindele niyii niluu Oba nibi to ti n yo ayo ojo ibi re to ko laipe yii (August 24). Ka ma paro, Funke Akindele ta lenu! La...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)