Jegudujera: Ile ejo siwe esun Saraki lakotun Olayemi Oniroyin 3/13/2016 08:34:00 am Add Comment Edit Awon Yooba bo, won tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Ibi aroko ti si, ibe naa la a fabo si. Eleyii gele ni se apejuwe aare... Read More
Iji nla ja nile igbimo asofin ipinle Ondo Olayemi Oniroyin 3/13/2016 08:28:00 am Add Comment Edit *Won yo adari ile igbimo asofin, won tun da a pada lojo keji. Awon omo ile igbimo asofin ipinle Ondo gbimopo yo adari ile, A... Read More
Buhari toro aforijin lowo omo Naijiria latari ina elentiriki to daku Olayemi Oniroyin 3/13/2016 08:23:00 am Add Comment Edit *”Falala ni awon eniyan yoo ma gbadun ina elentiriki lati ose yii lo” - Lai Muhammed Aare Muhammadu Buhari Latari ina monamona ele... Read More
E wo ohun ti Rotimi Amaechi se niluu Abuja Olayemi Oniroyin 3/12/2016 08:41:00 pm Add Comment Edit Rotimi Amaechi, Minisita fun igbokegbodo oko, se iranwo fun awon osise ijoba to pade lona nipa fifi oko re gbe won de ibi ise won niluu ... Read More
Won fi ibon ko ifun omo ileewe jade ni Mile 12 Olayemi Oniroyin 3/12/2016 08:30:00 pm Add Comment Edit * Oba Akiolu fara mo aba Ambode lati gbe oja Mile 12 kuro Leyin rogbodiyan to be sile ni agbegbe Mile 12 to kale siluu Eko laaar... Read More