Ọjọ́ ìbí olùkọ́ mi : Omowe Clement Odoje Olayemi Oniroyin 9/29/2019 01:51:00 pm Add Comment Edit Omowe Clement Odoje Bí babaláwo bá ń sọdún Ifá Won a mú Ifá ire kawo tí ń sọdún Orunmila. Pasitọ kò ní ṣajọdun kí wọn má ká Sáàmù ... Read More
Sí Abiodun Olanrewaju ọ̀rẹ́ mi Olayemi Oniroyin 9/29/2019 08:05:00 am Add Comment Edit Olanrewaju kú Ojúmọ́. Má gbàgbé ọ̀rọ̀ tí mo bọ́ ọ sọ lóru àná. Jẹ ọlọ́gbọ́n, ó ti kúrò lọmọde. Bí ẹnikẹ́ni bá ṣẹ ọ má bínú tán. ... Read More
Ọ̀nà àbáyọ fún àwọn tó bá ní oòrùn ara (Body Odour) Olayemi Oniroyin 9/27/2019 11:32:00 pm Add Comment Edit Ǹjẹ́ ẹ ṣe àkíyèsí wí pé ẹni oòrùn ara (Body Odour)? Ohùn tí ẹ lè ṣe ni yìí ti e ba ni òórùn ara (body odour). Ẹ wá ọsan wẹẹrẹ eleyii ti wọ... Read More
Hubert Ogunde: Ohun tí àwọn onsọ̀tàn sọ nípa ìbẹ̀rẹ̀ tíátà Nigeria Olayemi Oniroyin 9/26/2019 10:58:00 am Add Comment Edit Hubert Ogunde Ko ̀ si ́ bi ́ a s ̣ e fe ̣ ki ́ Ì ba ̀ da ̀ n la ́ i ̀ me ̣́ nu ba àru ̀ n Ìba ̀ da ̀ n; sebi ́ wo ̣́ n... Read More
Iporuuru ọkàn: Ajakalẹ àrùn tí ń yọ Nigeria lẹ́nu Olayemi Oniroyin 5/26/2019 07:49:00 am Add Comment Edit Tí a bá ń parọ fún ara wa ni a má fi ọ̀rọ̀ sì abẹ ahọn sọ. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ sì ni wi pe nǹkan burú síi ní fún orile-ede Nàìjíríà. Àpẹẹrẹ wí pé ... Read More