Awon olopa Ipinle Ogun ti gbe Kayode Olubunmi, eni odun metadinlogoji pelu bi o se binu naa aburo re, Haruna Adeoye to je eni ogun odun pa tori iresi odun keresimesi ni ile won to wa ni Ajegunle, Ita-Oluwo, Ogijo ni ijoba ibi Sagamu.
Kayode na ibatan re to tun je bi aburo si, eni ti o n gbe pelu re latari wi pe o je gbogbo iresi odun ti won wa gbe fun won eleyii to so fun aburo re wi pe ko toju ki awon le ri fi jeun ale ni ale ojo keresimesi (25/12/13).
Sugbon nigba ti Kayode yoo fi wole de ni ale ojo odun, omo okunrin naa ti mu otin yo keri, ibinu abisodi lo si fi na aburo re ni ana pa.
Awon olopa Eleweran ti gbe Olubumi, won si ni yoo foju ba ile ejo laipe.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment