Okunrin Aramanda Lati Ilu Holand Ti Di Kayeefi Fun Gbogbo Aye Olayemi Oniroyin 6/21/2014 12:24:00 am Add Comment Edit Bi ojumo ba se n mo ni awon ohun ti ko sele ri yoo maa waye ti yoo si dabi kayeefi loju omo eniyan. Sugbon pupo iru awon nnkan wonyii ni ... Read More
Omu Nla Bi Ogede Agbagba Fo Yangayanga Olayemi Oniroyin 6/18/2014 10:47:00 pm Add Comment Edit Kim Brockhurst, eni odun mokanlelaadota (51) lo na owo ti isiro re n lo bi milionu kan owo naira (1M) lati so omu aya re di shikishiki. S... Read More
Boko Haram Ilu Kenya Pa Aimoye Eniyan Nibi Won Ti Woran Boolu Agbaye Olayemi Oniroyin 6/16/2014 11:00:00 pm 2 Comments Edit Ko si ibi ti Boko Haram ko si lagbaye, oruko ti won je lo yato si ara awon. Awon iko ologun alakatakiti esin Islam ti ilu Somalia ti ise ... Read More
Adun Ere Ife Ti Pa Omo Baba Olowo Ni Ilu London Olayemi Oniroyin 6/12/2014 03:00:00 am Add Comment Edit Anastasia Tutik omo baba olowo to je eni odun mokandilogun(19) lo jabo pelu ololufe re to je eni odun mejidinlogun lati faranda to wa lori ... Read More
Ogorun Marun-un Oloyun Jo Skelewu Ni Ilu China Loju Kan Naa Olayemi Oniroyin 6/10/2014 01:04:00 am Add Comment Edit Ilu China ti fi ipa tuntun sile lagbaye pelu bi awon oloyun bi ogoruun marun-un ati marun (505) se gbarijo si oju kan lati se idaraya ele... Read More