Fayose ṣeleri itẹsiwaju rẹ gẹgẹ bi alatako iṣejọba Buhari Olayemi Oniroyin 1/31/2016 10:56:00 am Add Comment Edit Fayose ṣe abẹwo si ipinlẹ Ọsun lori isọkan ọmọ Oduduwa “Mi o yan Arẹgbesọla gẹgẹ bi ẹlẹbẹ si Buhari”- Fayose Fayose ati Aregbes... Read More
“Lilo ileewe fun ipatẹ ariya nipinle Eko ti deewọ”- Ambode Olayemi Oniroyin 1/31/2016 08:00:00 am Add Comment Edit *Ambode fẹ ra ẹrọ ayarabiasa pelebe 324, 000 fun awon akekọọ Akinwunmi Ambode Ijọba ipinlẹ Eko ti kede wi pe, ko saaye fun ... Read More
Ayẹyẹ ọjọ ibi Amosun kọyọyọ l’Ẹgba Alake Olayemi Oniroyin 1/30/2016 07:41:00 pm Add Comment Edit *Wale Dada ni ojiṣẹ Ọlọrun ni gomina Amosun ati awon komisanna re "Ohun idunnu julọ ati ẹkunrẹrẹ ayọ ni imuṣẹ awọn iler... Read More
Aga Faleke sofo lọjọ ti wọn jẹ gomina tuntun ni Kogi Olayemi Oniroyin 1/30/2016 12:30:00 pm Add Comment Edit *“Wọn ko pe mi sibi ibura gomina tuntun "- Faleke *Faleke fi aidunnu rẹ han si alaga APC apapọ Yahaya Bello Ipinlẹ ... Read More
Tinubu wo ilu Ibadan nile Oluyole Olayemi Oniroyin 1/24/2016 11:11:00 pm Add Comment Edit Oloye Bola Tinubu wo ilu Ibadan lati wa ba idile Oba Samuel Odulana to waja kedun. Sugbon ile ijoba ipinle Oyo lo koko gba lo lati se... Read More