Eleyii to kere ju, lo buru ju lo Olayemi Oniroyin 4/11/2016 03:33:00 pm Add Comment Edit Eleyii to kere ju, lo buru ju lo Eran nla, eran agbija, leran ti won pe ni kunnugba. Awon agba ode gba wi pe, eniyan bi meje (7) l... Read More
Tomode ba subu… Olayemi Oniroyin 3/20/2016 09:10:00 pm Add Comment Edit Ni awon akoko kan ninu igbesi aye wa, o ye ki a maa duro lati se asaro ati arojinle nipa awon igbese wa gbogbo. Se a n tesiwaju ni a... Read More
Akoko eda mbe lowo Oluwa oba Olayemi Oniroyin 3/14/2016 09:04:00 am Add Comment Edit Olajumoke Orisaguna E ku asiko yii, eyin eniyan mi. Nje eyin tile mo wi pe oju ojo ilu Kenya n fi wakati meji (2hrs) sare ju til... Read More
Ipo wo ni iwo fe wa ninu awon olowo ile Afirika? Olayemi Oniroyin 3/05/2016 08:30:00 pm Add Comment Edit Mike Adenuga Ni owuro yii, mo fi akoko mi sile lati ka nipa aseyori Mike Adenuga, alase ati oludari ile ise ibanisoro Gbobacom. Ohun t... Read More
Olajumoke omo oniburedi Olayemi Oniroyin 2/28/2016 09:18:00 pm Add Comment Edit Olajumoke Orisaguna Opolopo ni i pokiki Olajumoke Orisaguna omo oniburedi gege bi oloriire ti Edumare da lola ojiji pelu bo se se ... Read More
Falana gbo tie… Olayemi Oniroyin 1/24/2016 10:22:00 pm Add Comment Edit Awon Yoruba ni tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Lose to koja lo loun ni mo n so idi pataki ti a fi gbodo maa fi o ker... Read More
Tina ba n joni, ti n jo omo eni… Olayemi Oniroyin 1/12/2016 08:47:00 pm Add Comment Edit #ogulutu #13 Owo tabua le mi n fe... Odun tuntun ti bere. Bi eniyan se ipinnu, bi eniyan gbadura dola, ti eni naa ko ba gbe igbe... Read More
Igbese, akoko ati agbara fun odun 2016 Olayemi Oniroyin 12/26/2015 10:04:00 pm Add Comment Edit #ogulutu #12 Ti eniyan ba fi opolo sinu ikoko-isebe kan ti omi kun inu re, ki eniyan wa gbe ikoko naa ka ori ina. Bi ina se n jo, t... Read More
Lati je eniyan alagbara lodun 2016 Olayemi Oniroyin 12/19/2015 12:38:00 pm Add Comment Edit #Ogulutu #11 Nigba ti a wa ni kekere, ti awon obi wa ba sakiye wi pe a n ko awon ore ti ko dara. Iru gbolohun yii maa n jade le... Read More
Igbaradi fun odun 2016 Olayemi Oniroyin 12/16/2015 06:13:00 pm 4 Comments Edit #Ogulutu #10 Bi odun se n pari lo, dandan ni fun wa lati wa ni igbaradi fun odun tuntun. O se pataki, ki a ma ba a bo sinu awon... Read More
December: Eda to ba monu ro… Olayemi Oniroyin 12/06/2015 10:13:00 am Add Comment Edit #Ogulutu #9 Ti a ba ranti ibi taa ti n bo, ti a ba si sakiyesi ibi taa de ninu igbe aye wa, idi ope wa yoo foju han gban-angba. ... Read More
Amukun-un, eru re wo… Olayemi Oniroyin 12/03/2015 10:11:00 pm Add Comment Edit #Ogulutu #8 Lara isoro nla ti ile Naijiria n koju lonii ni isoro airise awon odo. Isoro kan soso yii si ti bi aimoye isoro kale... Read More
Atelewo eni ki i tanni i je Olayemi Oniroyin 11/25/2015 10:33:00 am Add Comment Edit #Ogulutu #7 Wole Soyinka A won Yoruba bo, won ni amukun-un eru re wo, o ni oke le n wo, e wole. Ojuse awon obi ki i se lati pes... Read More
#Ogulutu: Atelewo ni mo bala (2) Olayemi Oniroyin 11/14/2015 09:52:00 pm Add Comment Edit #Ogulutu #6 Ki n to so die fun yin lara itan igbesi aye mi kan ti mi o le gbagbe laelae. Se e ko gbagbe alaye ti mo se fun y... Read More
#OGULUTU: Atelewo ni mo bala Olayemi Oniroyin 11/08/2015 05:23:00 pm Add Comment Edit Atelewo ni mo bala #OGULUTU #5 Eyin eniyan mi, ohun kan to daju ni wi pe ko si enikeni ti Olorun oba ko fun lebun kan to joju. Ele... Read More
#Ogulutu: Iwon ese bata kan pere: E kaabo sinu osu tuntun Olayemi Oniroyin 11/01/2015 04:44:00 pm Add Comment Edit #Ogulutu #4 Eyin eniyan mi, n maa ki yin kaabo sinu osu tuntun pelu itan Ogbeni Darby omo ilu Amerika to ti n tawo-tase ninu mi fun... Read More
#Ogulutu: Ati kekere ni musulumi ti n ko omo re laso Olayemi Oniroyin 10/24/2015 06:57:00 pm Add Comment Edit #Ogulutu #3 Ati kekere ni musulumi ti n ko omo re laso E je ki n so itan kekere kan fun yin. Pasito kan an gbiyanju lojo Sati... Read More
Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata (2) Olayemi Oniroyin 10/19/2015 10:01:00 am 2 Comments Edit #Ogulutu Nigba ti mo wa ni kekere, awon egbon adugbo kan wa, awon ti awon obi wa gba wi pe won nimo ju wa lo. Read More
#OGULUTU: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata Olayemi Oniroyin 10/11/2015 03:11:00 pm Add Comment Edit #OGULUTU #1 E ku asiko yii eyin eniyan mi, ko to di wi pe n maa se alaye ara mi tabi abala Ogulutu to je tuntun to gori Iwe Iroyin ... Read More